[Intro]
Oh oh oh
Nobody can take away my throne
Nobody can take away
Huh my throne oh oh
[Verse]
The throne is mine – moment of clarity
Lọ́jọ́ timo rí competition mo fi opponent mise charity
Awa ti ń kick bars láti inú oyún my matter be don pass maternity
Agbomola to gbebimi ni make dem use me do trade by barter for vanity
My new tune ìtumọ̀ tuntun fún aro àpèjúwe insanity
I’m better than everyone irrespective of your ethnicity
So Yoruba, Ibo lè pọ mọ Hausa síbẹ̀ ó temiti
Olè tí Eckanker wo Christianity – àmọ́ ojo tó bá komi lo encounter reality
Realness mio ni measure – I will be a treasure to your forefather
Dem say naira still dey drop tinba gbayin mú you go fall harder
Everything I spit is spirit filled – Revelation to the lost chapter
Orin mí dùn ju sugar lọ that’s why na me dem dey sought-after
Èmi all about the dope shit – èmi àti wack akin relate
Mo tán ju gbogbo aiye nínú fluorescent ṣe ọpọlọ yín assimilate
If I ain’t the next best I’m the best already
Afin min nbẹ nínú ọrùn àwọn afin ofe bami affiliate
I do what the best can’t – do what the rest don’t
Mio deni rest tinma fi ní hit ju restaurant
Won wa mi leni wọn rí mi lola like odi next month
Afola Afola you no go fit be my type gbàgbé nípa text font
I pledge to Africa my continent never to take an oath
Swear by the closest cemetery èyin ni meeh èmi ni goat
Fi middle finger te ballot paper like helf ya vote
Èmi ni Kabiyesi rap, trap lórí Afro Beat better go take ya note
I am more than just a man – six cubit and span
Ani mo fresh – Peter Pan – You not a fan you a stan
Understand – kami kami yàtọ̀ sí ka sunmu
Yall still won’t be up to par be ti ẹ yí orúkọ yín pada si Kasunmu
So ki le nkọ tèmi yọ – mo jáwọ́n kosi iyọ̀
Ẹ jáwọ́ lápọ̀n tí ó yọ – èmi lọ tá bodi ayọ̀
Ama veteran joo – And I’m better than yall
Èmi àti Aláàfin Ọ̀yọ́ wé be laughing at yall
Like àwọn eléyìí ó ti ẹ mọ bó ṣe ń lọ sha
Sharia constitution lori track mo koun sha gbogbo wọn lọ sha
Moti gbaná ó moti elevate
O yẹ ki YBNL tí sign mi I can barely wait
Àmọ́ èmi àti laptop mi oshe seperate
Síbẹ̀ ó de làwọn kan toti rẹ timo fewa relegate
The throne is mine – ẹ dìde lórí ìtẹ́ mi ẹ ti tó ọba je
Name me king – yall claiming king etí soba Plus I do all the killings really you all got me feeling like
Èlé rí ọba jẹ igbẹyin ọba tòun foba jẹ níwájú ọba tòun pobaje
Ọba tantanla ni yín èmi ni Obatala àkọ́bí Lamurudu
Akomolode number two – Kìnnìún ẹeya àwọn aláwọ̀ dúdú
Ooni Ifè àti Ọba ìlú daddy yín ín body
Bẹ dá Odùduwà padà wá gàn kosi nkankan tó lè bami dù
King of the North East West South àti middle belt
King of the kill em I ain’t never scared of your needle threat
Industry ti gbà àlejò nanpe but when I do it mo she bí vet
And if you think that one e go be joke you all still ain’t get a riddle yet
Ama conqueror kodesi kọ́kọ́rọ́ fún ilẹkun tábà tí ti
Won fe se bí ọba kò sese wọn sise dey enter calamity
Ìṣubú kabiti – mental capacity mi ń fún wọn ní dental cavity
Mo lè fi one verse kò gbogbo universe losi University
[Hook]
Emi number – èmi number one- èmi number one
Èmi lọba – èmi lọba wọn – èmi loba wọn
But I see too many thieves – too many thieves tryna steal my shine
Too many chieves – too many chieves but the throne is mine
Leave a Reply